Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Paul: Dwells two years in his own hired house, preaching and teaching
Àwọn ẹsẹ nípa Dwells two years in his own hired house, preaching and teaching
Paulu sì gbé ilé àgbàwọ̀ rẹ̀ lọ́dún méjì gbáko, ó sì ń gbà gbogbo àwọn tí ó wọlé tọ̀ ọ́ wá.
Ó ń wàásù ìjọba Ọlọ́run, ó ń fi ìgboyà kọ́ni ní àwọn ohun tí i ṣe ti Jesu Kristi Olúwa, ẹnìkan kò si dá a lẹ́kun.