Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Paul: Has Barnabas as his companion

2 ẹsẹ · 103 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Has Barnabas as his companion

  1. Barnaba sì jáde lọ sí Tarsu láti wá Saulu,

  2. nígbà tí ó sì rí i, ó mú un wá sí Antioku. Fún ọdún kan gbáko ni wọ́n fi ń bá ìjọ péjọpọ̀, tí wọ́n sì kọ́ ènìyàn púpọ̀. Ní Antioku ni a sì kọ́kọ́ ti pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ni “Kristiani.”