Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Syria: Terror and dismay in, occasioned by its invasion

2 ẹsẹ · 61 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Terror and dismay in, occasioned by its invasion

  1. Nípa Damasku. “Inú Hamati àti Arpadi bàjẹ́ nítorí wọ́n gbọ́ ìròyìn búburú, ìjayà dé bá wọn, wọ́n sì dààmú bí omi Òkun.

  2. Damasku di aláìlera, ó pẹ̀yìndà láti sálọ, ìwárìrì sì dé bá a; ìbẹ̀rù àti ìrora dìímú, ìrora bí ti obìnrin tí ó wà ní ipò ìrọbí.