Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Syria: In the time of Abraham it seems to have embraced the region between the rivers Tigris and Euphrates

2 ẹsẹ · 61 abala

Àwọn ẹsẹ nípa In the time of Abraham it seems to have embraced the region between the rivers Tigris and Euphrates

  1. Ìránṣẹ́ náà sì mú ìbákasẹ mẹ́wàá, pẹ̀lú onírúurú ohun dáradára láti ọ̀dọ̀ olúwa rẹ̀, ó sì dìde ó sì lọ sí Aramu-Naharaimu, sí ìlú Nahori,

  2. Nígbà tí Isaaki di ọmọ ogójì ọdún ni ó gbé Rebeka ọmọ Betueli ará Aramu ti Padani-Aramu tí í ṣe arábìnrin Labani ará Aramu ní ìyàwó.