Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Syria: Obtained renown by his victory over
Àwọn ẹsẹ nípa Obtained renown by his victory over
Dafidi sì ní òkìkí gidigidi nígbà tí ó padà wá ilé láti ibi pípa àwọn ará Siria ní àfonífojì Iyọ̀, àwọn tí o pa jẹ́ ẹgbàá mẹ́sàn (18,000) ènìyàn.