Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Syria: Destroyed the army of, which assisted Hadadezer
Àwọn ẹsẹ nípa Destroyed the army of, which assisted Hadadezer
Nígbà tí àwọn ará Siria ti Damasku sì wá láti ran Hadadeseri ọba Soba lọ́wọ́, Dafidi sì pa ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000) ènìyàn nínú àwọn ará Siria.