Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Syria: Retook Elath and drove out the Jews
Àwọn ẹsẹ nípa Retook Elath and drove out the Jews
Ní àkókò náà, Resini ọba Siria gba Elati padà fún Siria, ó sì lé àwọn ènìyàn Juda kúrò ní Elati: àwọn ará Siria sì wá sí Elati, wọ́n sì ń gbé ibẹ̀ títí di òní yìí.