Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Syria: Its calamities, the punishments of its sins
Àwọn ẹsẹ nípa Its calamities, the punishments of its sins
Èyí ni ohun tí Olúwa wí: “Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta tí Damasku, àní fún mẹ́rin, Èmi kò ní yí ìpinnu ìjìyà mi padà. Nítorí wọn fi ohun èlò ìpakà pa Gileadi. Pẹ̀lú ohun èlò irin tí ó ní eyín mímú,