Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Syria: Paul preaches in

4 ẹsẹ · 61 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Paul preaches in

  1. Ó sì la Siria àti Kilikia lọ, ó ń mú ìjọ ní ọkàn le.

  2. Paulu sì dúró sí i níbẹ̀ lọ́jọ́ púpọ̀, nígbà tí ó sì dágbére fún àwọn arákùnrin, ó bá ọkọ̀ ojú omi lọ si Siria, àti Priskilla àti Akuila pẹ̀lú rẹ̀; ó tí fá orí rẹ̀ ni Kenkerea, nítorí tí ó ti jẹ́ ẹ̀jẹ́.

  3. Nígbà tí àwa sì ń wo Saipurọsi lókèèrè, a sì fi í sí ọwọ́ òsì, a fi orí ọ́kọ̀ le Siria, a sì gúnlẹ̀ ni Tire; nítorí níbẹ̀ ni ọkọ̀ yóò tí já ẹrù sílẹ̀.

  4. Lẹ́yìn náà mo sì wá sí agbègbè Siria àti ti Kilikia.