Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Syria: Destruction of Rezin king of

2 ẹsẹ · 61 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Destruction of Rezin king of

  1. nítorí Damasku ni orí Aramu, orí Damasku sì ni Resini. Láàrín ọdún márùnlélọ́gọ́ta Efraimu yóò ti fọ́ tí kì yóò le jẹ́ ènìyàn mọ́.

  2. Ṣùgbọ́n kí ọ̀dọ́mọkùnrin náà tó mọ bí a ti ń kọ ẹ̀bi àti láti yan rere, ilẹ̀ àwọn ọba méjèèjì tí ń bà ọ́ lẹ́rù wọ̀nyí yóò ti di ahoro.