Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Syria: People of, colonized in Samaria by the king of Assyria
Àwọn ẹsẹ nípa People of, colonized in Samaria by the king of Assyria
Ọba Asiria mú àwọn ènìyàn láti Babeli, Kuta, Afa, Hamati àti Sefarfaimi, wọ́n sì fi wọ́n sínú ìlú Samaria láti rọ́pò àwọn ọmọ Israẹli. Wọ́n sì ń gbé ní ìlú náà.