Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Saints: People of God
Àwọn ẹsẹ nípa People of God
nítorí náà ìsinmi kan kù fún àwọn ènìyàn Ọlọ́run.
Ẹ̀yin tí kì í ṣe ènìyàn nígbà kan rí, ṣùgbọ́n nísinsin yìí, ẹ̀yin ti di ènìyàn Ọlọ́run, ẹ̀yin tí kò rí àánú gbà rí, ṣùgbọ́n nísinsin yìí, ẹ ti rí àánú gbà.