Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Saints: Heirs of the kingdom
Àwọn ẹsẹ nípa Heirs of the kingdom
Ẹ fi etí sílẹ̀, ẹ̀yin ará mi olùfẹ́: Ọlọ́run kò ha ti yan àwọn tálákà ayé yìí láti jẹ́ ọlọ́rọ̀ nínú ìgbàgbọ́, àti ajogún ìjọba náà, tí ó ti ṣe ìlérí fún àwọn tí ó fẹ́ ẹ?