Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Saints: Joint-heirs with Christ
Àwọn ẹsẹ nípa Joint-heirs with Christ
Níwọ́n ìgbà tí a jẹ́ ọmọ rẹ̀, ǹjẹ́ ajogún ni àwa, ajogún Ọlọ́run, àti àjùmọ̀jogún pẹ̀lú Kristi, bí ó bá ṣe àwa jìyà, kí a sì le ṣe wá lógo pẹ̀lú rẹ̀.