Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Saints: Chosen vessels
Àwọn ẹsẹ nípa Chosen vessels
Ṣùgbọ́n Olúwa wí fún un pé, “Máa lọ; nítorí ohun èlò ààyò ni òun jẹ́ fún mi, láti gbé orúkọ mi lọ sí iwájú àwọn aláìkọlà, àti àwọn ọba, àti àwọn ọmọ Israẹli.