Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Saints: Children of the Lord
Àwọn ẹsẹ nípa Children of the Lord
Ọmọ Olúwa Ọlọ́run yín ni ẹ̀yin jẹ́: nítorí náà, ẹ má ṣe ya ara yín ní abẹ. Ẹ má ṣe gé irun iwájú orí yín nítorí òkú.