Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Saints: Fellow-citizens with the saints
Àwọn ẹsẹ nípa Fellow-citizens with the saints
Ǹjẹ́ nítorí náà ẹ̀yin kì í ṣe àlejò àti àjèjì mọ́, ṣùgbọ́n àjùmọ̀jogún ọmọ ìbílẹ̀ pẹ̀lú àwọn ènìyàn mímọ́, àti àwọn ará ilé Ọlọ́run;