Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Saints: Holy brethren
Àwọn ẹsẹ nípa Holy brethren
Mo pàṣẹ fún yín níwájú Olúwa pé, kí ẹ ka lẹ́tà yìí fún gbogbo àwọn ará.
Nítorí náà ẹ̀yin ará mímọ́, alábápín ìpè ọ̀run, ẹ gba ti aposteli àti olórí àlùfáà ìjẹ́wọ́ wa rò, àní Jesu;