Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Saints: Children of the Highest

1 ẹsẹ · 81 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Children of the Highest

  1. Ṣùgbọ́n kí ẹ̀yin fẹ́ àwọn ọ̀tá yín kí ẹ sì ṣoore, kí ẹ̀yin sì yá ẹlòmíràn, kí ẹ̀yin má ṣe retí láti rí nǹkan gbà padà; èrè yín yóò sì pọ̀, àwọn ọmọ Ọ̀gá-ògo ni a ó sì máa pè yín: nítorí tí ó ṣe rere fún aláìmoore àti fún ẹni búburú.