Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Saints: Faithful brethren in Christ
Àwọn ẹsẹ nípa Faithful brethren in Christ
Sí àwọn ẹni mímọ́ àti àwọn arákùnrin àti arábìnrin nínú Kristi tí wọ́n ń gbé ní ìlú Kolose: Oore-ọ̀fẹ́ àti àlàáfíà fún un yín láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba wa.