Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Saints: Friends of Christ

1 ẹsẹ · 81 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Friends of Christ

  1. Èmi kò pè yín ní ọmọ ọ̀dọ̀ mọ́; nítorí ọmọ ọ̀dọ̀ kò mọ ohun tí olúwa rẹ̀ ń ṣe, ṣùgbọ́n èmi pè yín ní ọ̀rẹ́ nítorí ohun gbogbo tí mo ti gbọ́ láti ọ̀dọ̀ Baba mi wá, mo ti fihàn fún yín.