Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Saints: Redeemed of the Lord

1 ẹsẹ · 81 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Redeemed of the Lord

  1. Àwọn ẹni ìràpadà Olúwa yóò padà wá. Wọn yóò wọ Sioni wá pẹ̀lú orin kíkọ; ayọ̀ ayérayé ni yóò sì bo orí wọn. Ayọ̀ àti inú dídùn yóò sì bà lé wọn ìbànújẹ́ àti ìtìjú yóò sì sá kúrò.