Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tabernacle: The table of show-bread, the golden candlestick, and the altar of incense were place in the holy place

5 ẹsẹ · 94 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The table of show-bread, the golden candlestick, and the altar of incense were place in the holy place

  1. Gbé tábìlì náà sí ìta aṣọ títa náà sí ìhà gúúsù àgọ́ náà, kí o sì gbé ọ̀pá fìtílà sí òdìkejì rẹ̀ ní ìhà àríwá.

  2. Mose gbé tábìlì sínú àgọ́ àjọ sí ìhà àríwá àgọ́ náà lẹ́yìn aṣọ títa,

  3. Ó gbé ọ̀pá fìtílà sínú àgọ́ àjọ ní òdìkejì tábìlì ní ìhà gúúsù àgọ́ náà.

  4. Mose gbé pẹpẹ wúrà sínú àgọ́ àjọ níwájú aṣọ títa

  5. A gbé àgọ́ kan dìde. Nínú yàrá rẹ̀ àkọ́kọ́ ni a ti rí ọ̀pá fìtílà, tábìlì, àti àkàrà ìfihàn. Èyí tí a ń pè ní ibi mímọ́.