Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tabernacle: Tabernacle of the congregation

3 ẹsẹ · 94 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Tabernacle of the congregation

  1. Ní àgọ́ àjọ, lẹ́yìn òde aṣọ ìkélé tí ó wá níwájú ẹ̀rí náà, Aaroni àti òun àti àwọn ọmọ rẹ̀, ni yóò tọ́jú rẹ̀ láti alẹ́, títí di òwúrọ̀ níwájú Olúwa: yóò sì di ìlànà láéláé ni ìrandíran wọn lọ́dọ̀ àwọn ọmọ Israẹli.

  2. Mose máa ń gbé àgọ́ náà, ó sì pa á sí ìta ibùdó, ó jìnnà díẹ̀ sí ibùdó, ó pè é ni “Àgọ́ àjọ.” Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń béèrè Olúwa yóò lọ sí ibi àgọ́ àjọ náà ní ìta ibùdó.

  3. Mose gbé pẹpẹ wúrà sínú àgọ́ àjọ níwájú aṣọ títa