Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tabernacle: The journeys of Israel regulated by the cloud on
Àwọn ẹsẹ nípa The journeys of Israel regulated by the cloud on
Ní gbogbo ìrìnàjò àwọn ọmọ Israẹli nígbàkígbà tí a bá ti fa ìkùùkuu àwọsánmọ̀ náà sókè kúrò lórí àgọ́, wọ́n máa ń jáde lọ;
ṣùgbọ́n tí àwọsánmọ̀ kò bá gòkè wọn kò ní jáde títí di ọjọ́ tí ó bá gòkè.