Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Priests: Required to prove their genealogy before they exercised the office

2 ẹsẹ · 86 abala

Wá "Priests"

Àwọn ẹsẹ nípa Required to prove their genealogy before they exercised the office

  1. Àwọn wọ̀nyí wá ìwé ìrántí ìdílé wọn, ṣùgbọ́n wọn kò rí i, bẹ́ẹ̀ ni a kò kà wọ́n kún ara àlùfáà nítorí, a kà wọ́n sí aláìmọ́.

  2. Àwọn wọ̀nyí wá àkọsílẹ̀ orúkọ ìran wọn, ṣùgbọ́n wọn kò rí í níbẹ̀, fún ìdí èyí, a yọ wọ́n kúrò nínú àwọn tí ń ṣiṣẹ́ àlùfáà gẹ́gẹ́ bí aláìmọ́.