Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Priests: First notice of persons acting as

2 ẹsẹ · 86 abala

Àwọn ẹsẹ nípa First notice of persons acting as

  1. Ó sì ṣe lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, Kaini mú ọrẹ wá fún Olúwa nínú èso ilẹ̀ rẹ̀.

  2. Ṣùgbọ́n Abeli mú ẹran tí ó sanra wá fún Olúwa nínú àkọ́bí ẹran ọ̀sìn rẹ̀. Olúwa sì fi ojúrere wo Abeli àti ọrẹ rẹ̀,