Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Priests: A fixed portion of the spoil taken in war
Àwọn ẹsẹ nípa A fixed portion of the spoil taken in war
Gba ìdá yìí lára ààbọ̀ ìpín tiwọn, kí o sì fún Eleasari àlùfáà, fún ẹbọ ìgbésókè Olúwa.
Mose fi ìdá náà fún Eleasari, àlùfáà gẹ́gẹ́ bí ìdá ti Olúwa, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pa á láṣẹ fún Mose.