Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Priests: Anointing with oil

2 ẹsẹ · 86 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Anointing with oil

  1. “Ìwọ yóò sì ta òróró sí orí Aaroni àti àwọn ọmọ rẹ̀, ìwọ yóò sì sọ wọ́n di mímọ́, nítorí kí wọn lè sìn mí bí àlùfáà.

  2. Nígbà náà wọ Aaroni ní aṣọ mímọ́, ta òróró sí i ní orí, kí o sì yà á sí mímọ́, nítorí kí ó lè máa sìn mi bí àlùfáà.