Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Priests: Worn by the high priest on the day of atonement
Àwọn ẹsẹ nípa Worn by the high priest on the day of atonement
Òun yóò sì wọ aṣọ funfun mímọ́ pẹ̀lú àwọ̀tẹ́lẹ̀ funfun, yóò sì fi àmùrè funfun mímọ́ dì í, yóò sì dé fìlà funfun, àwọn aṣọ mímọ́ nìwọ̀nyí. Òun yóò sì fi omi wẹ̀, kí ó tó wọ̀ wọ́n.