Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Trees: Designed to beautify the earth
Àwọn ẹsẹ nípa Designed to beautify the earth
Olúwa Ọlọ́run sì mú kí onírúurú igi hù jáde láti inú ilẹ̀, àwọn igi tí ó dùn ún wò lójú, tí ó sì dára fún oúnjẹ. Ní àárín ọgbà náà ni igi ìyè àti igi tí ń mú ènìyàn mọ rere àti búburú wà.