Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Trees: Often propagated by birds who carry the seeds along with them

2 ẹsẹ · 87 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Often propagated by birds who carry the seeds along with them

  1. Sọ fún wọn pé, ‘Báyìí ni Olúwa Olódùmarè wí, idì ńlá kan tó ní apá títóbi àti ìyẹ́ gígùn tó kún fún àwọ̀ oríṣìíríṣìí wa si Lebanoni, ó sì mu ẹ̀ka igi kedari tó ga jùlọ,

  2. “ ‘Ó mú lára irúgbìn ilẹ̀ náà, ó gbìn ín sí ilẹ̀ ọlọ́ràá, lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ omi, ó gbìn ín bí igi wílóò.