Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Trees: (Casting their leaves yet retaining their substance,) of the elect remnant in the church
Àwọn ẹsẹ nípa (Casting their leaves yet retaining their substance,) of the elect remnant in the church
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìdámẹ́wàá ṣẹ́kù lórí ilẹ̀ náà, yóò sì tún pàpà padà di rírun. Ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí igi tẹrẹbinti àti igi óákù, ti í fi kùkùté sílẹ̀ nígbà tí a bá gé wọn lulẹ̀, bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni irúgbìn mímọ́ náà yóò di kùkùté ní ilẹ̀ náà.”