Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Trees: Specially flourished beside the rivers and streams of water

1 ẹsẹ · 87 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Specially flourished beside the rivers and streams of water

  1. Àwọn igi eléso ní oríṣìíríṣìí ni yóò máa hù ní bèbè odò ní ìhà ìhín àti ní ìhà ọ̀hún. Ewé wọn kì yóò sì rọ, bẹ́ẹ̀ ní èso wọn kì yóò run, wọn yóò máa ṣe èso tuntun rẹ̀ ní oṣù nítorí pé omi láti ibi mímọ́ ń sàn sí wọn. Èso wọn yóò sì jẹ́ fún jíjẹ àti ewé wọn fún ìwòsàn.”