Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Trees: (Producing evil fruit,) of the wicked
Àwọn ẹsẹ nípa (Producing evil fruit,) of the wicked
Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo igi rere a máa so èso rere ṣùgbọ́n igi búburú a máa so èso búburú.
Igi rere kò le so èso búburú, bẹ́ẹ̀ ni igi búburú kò lè so èso rere.
Gbogbo igi tí kò bá so èso rere, a gé e lulẹ̀, à wọ́ ọ jù sínú iná.