Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Trees: Prohibited from cutting down fruit bearing, for sieges
Àwọn ẹsẹ nípa Prohibited from cutting down fruit bearing, for sieges
Nígbà tí o bá dó ti ìlú kan láti ọjọ́ pípẹ́, ẹ bá wọn jà láti gbà á, má ṣe pa àwọn igi ibẹ̀ run nípa gbígbé àáké lé wọn, nítorí o lè jẹ èso wọn. Má ṣe gé wọn lulẹ̀. Nítorí igi igbó ha á ṣe ènìyàn bí, tí ìwọ ó máa dó tì rẹ̀.