Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Scriptures: Are profitable both for doctrine and practice
Àwọn ẹsẹ nípa Are profitable both for doctrine and practice
Gbogbo ìwé mímọ́ ni ó ní ìmísí Ọlọ́run tí ó sì ní èrè fún ẹ̀kọ́, fún ìbániwí, fún ìtọ́ni, fún ìkọ́ni tí ó wà nínú òdodo.
Kí ènìyàn Ọlọ́run lè pé, tí a ti múra sílẹ̀ pátápátá fun iṣẹ́ rere gbogbo.