Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Scriptures: All should desire to hear
Àwọn ẹsẹ nípa All should desire to hear
gbogbo àwọn ènìyàn kó ara wọn jọ bí ẹnìkan ní gbangba ìta níwájú ibodè omi. Wọ́n sọ fún Esra akọ̀wé pé kí ó gbé ìwé òfin Mose jáde, èyí tí Olúwa ti pàṣẹ fún Israẹli.