Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Scriptures: Admonishing

2 ẹsẹ · 108 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Admonishing

  1. Nípa wọn ni a ti ṣí ìránṣẹ́ rẹ̀ létí; nípa pípa wọ́n mọ́, èrè púpọ̀ ń bẹ.

  2. Gbogbo àwọn nǹkan wọ̀nyí ṣẹlẹ̀ sí wọn bí àpẹẹrẹ fún wa, a sì kọ̀wé wọn fún ìkìlọ̀ fún wa, àwa ẹni tí ìgbẹ̀yìn ayé dé bá.