Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Scriptures: Pray to be taught
Àwọn ẹsẹ nípa Pray to be taught
Ìyìn ni fún Olúwa; kọ́ mi ní àṣẹ rẹ.
Pẹ̀lú ètè mi èmi tún ṣírò gbogbo òfin tí ó wá láti ẹnu rẹ.
Kọ́ mi, Olúwa, láti tẹ̀lé àṣẹ rẹ; nígbà náà ni èmi yóò pa wọ́n mọ́ dé òpin.
Kọ́ mi ní ìmọ̀ àti ìdájọ́ rere, nítorí mo gbàgbọ́ nínú àṣẹ rẹ.