Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Scriptures: The letter of, without the spirit, killeth

2 ẹsẹ · 108 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The letter of, without the spirit, killeth

  1. Ẹ̀mí ní ń sọ ni di ààyè; ara kò ní èrè kan; ọ̀rọ̀ wọ̀nyí tí mo sọ fún yín, ẹ̀mí ni, ìyè sì ni pẹ̀lú.

  2. Ẹni tí ó mú wa yẹ bí ìránṣẹ́ májẹ̀mú tuntun; kì í ṣe ní ti ìwé àkọsílẹ̀ ṣùgbọ́n ní ti ẹ̀mí, nítorí ìwé a máa pa ni, ṣùgbọ́n ẹ̀mí a máa sọ ní di ààyè.