Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Scriptures: Word of Christ

1 ẹsẹ · 108 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Word of Christ

  1. Ẹ jẹ́ kí ọ̀rọ̀ Kristi máa gbé inú yín ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú ọgbọ́n gbogbo; kí ẹ máa kọ́ ọ, kí ẹ sì máa gba ara yín níyànjú nínú Saamu, àti orin ìyìn, àti orin ẹ̀mí, ẹ máa kọrin sí Ọlọ́run ní ọkàn ọpẹ́.