Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Scriptures: They who search, are truly noble
Àwọn ẹsẹ nípa They who search, are truly noble
Àwọn Júù Berea sì ní ìyìn ju àwọn tí Tẹsalonika lọ, ní tí pé wọn fi tọkàntọkàn gbà ọ̀rọ̀ náà. Wọ́n sì ń wá inú ìwé mímọ́ lójoojúmọ́ bí nǹkan wọ̀nyí bá rí bẹ́ẹ̀.