Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Scriptures: Nothing to be taken from, or added to

2 ẹsẹ · 108 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Nothing to be taken from, or added to

  1. Ẹ má ṣe fi kún àwọn ohun tí mo pàṣẹ fún un yín, ẹ kò sì gbọdọ̀ yọ kúrò nínú wọn, ṣùgbọ́n ẹ pa òfin Olúwa Ọlọ́run yín tí mo fún un yín mọ́.

  2. Ẹ rí i pé ẹ̀ ń ṣe gbogbo ohun tí mo ti pàṣẹ fún un yín. Ẹ má ṣe fi kún un, ẹ má sì ṣe yọ kúrò níbẹ̀.