Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Servants: Maimed of injured by masters to have their freedom

2 ẹsẹ · 147 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Maimed of injured by masters to have their freedom

  1. “Bí ọkùnrin kan bá lu ẹrúkùnrin tàbí ẹrúbìnrin rẹ̀ ní ojú, ti ojú náà sì fọ́, ó ni láti jẹ́ kí ẹrú náà lọ ní òmìnira fún ìtánràn ojú rẹ̀ ti ó fọ́.

  2. Bí ó bá sì lu ẹrúkùnrin tàbí ẹrúbìnrin rẹ̀ ti eyín rẹ̀ fi ká, ó ni láti jẹ́ kí ó lọ ní òmìnira ni ìtánràn fún eyín rẹ̀ tí ó ká.