Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Servants: To revere them the more, when they are believers

1 ẹsẹ · 147 abala

Àwọn ẹsẹ nípa To revere them the more, when they are believers

  1. Àwọn ti ó ní ọ̀gá onígbàgbọ́, kí wọn má ṣe ṣàìbọ̀wọ̀ fún wọn nítorí tí wọn jẹ́ arákùnrin; ṣùgbọ́n kí wọn túbọ̀ máa sìn wọ́n, nítorí àwọn tí í ṣe alábápín iṣẹ́ rere wọn jẹ́ onígbàgbọ́ àti olùfẹ́. Nǹkan wọ̀nyí ni kí ó máa kọ́ ni, kí o sì máa fi gbani níyànjú.