Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Servants: Servants of Boaz
Àwọn ẹsẹ nípa Servants of Boaz
Nígbà náà ni Boasi dé láti Bẹtilẹhẹmu tí ó sì kí àwọn olùkórè wí pé, “Kí Olúwa wà pẹ̀lú yín.” Wọ́n sì dá a lóhùn pé, “Kí Olúwa bùkún fún ọ.”