Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Servants: Strangers sojourning in Israel might be purchased as
Àwọn ẹsẹ nípa Strangers sojourning in Israel might be purchased as
Bákan náà, ẹ sì le è ra àwọn àlejò tí ń gbé láàrín yín, àti àwọn ìdílé wọn tí a bí sáàrín yín. Wọn yóò sì di ohun ìní yín.