Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Servants: To be esteemed worthy of their hire
Àwọn ẹsẹ nípa To be esteemed worthy of their hire
Ẹ dúró sínú ilé náà, kí ẹ máa jẹ, kí ẹ sì máa mu ohunkóhun tí wọ́n bá fi fún yín, nítorí ọ̀yà alágbàṣe tọ́ sí i. Ẹ má ṣe lọ láti ilé dé ilé.