Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Servants: Could not when set free demand wives or children procured during servitude

2 ẹsẹ · 147 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Could not when set free demand wives or children procured during servitude

  1. Bí ó bá wá ní òun nìkan, òun nìkan náà ni yóò padà lọ ní òmìnira; ṣùgbọ́n tí ó bá mú ìyàwó wá, ó ní láti mú ìyàwó rẹ̀ padà lọ.

  2. Bí olówó rẹ̀ bá fún un ní aya, tí aya náà sì bímọ ọkùnrin àti obìnrin, aya àti àwọn ọmọ rẹ̀ yóò jẹ́ ti olówó rẹ̀, yóò sì lọ ní òmìnira ní òun nìkan.